BAWO LOSE NLO
Written by Morenike Adebayo on March 2, 2015
Eku dede iwo yi o eyin ololofe wa , se alafia lewa? Se e o gbagbe pe to ba tidi dede ago mewa owuro oni ni ao ma pade lori akotun eto bawo lose nlo ni ile ise royalfm95.1 ilorin pelu emi Sherifat kayode bolaji skb lati maa mon bose lo lodo yin. E si le pewa sori awon opo yi 08108501371 tabi 08050999966 e maa miss e!