Bawo lose nlo

Written by on March 9, 2015

E kaaro o eyin ololufe wa, se e o gbagbe pe toba tidi ago mewa owuro oni 10-11am  ni e o tun pade emi SHERIFAT KAYODE BOLAJI lori eto BAWO LOSE NLO ni ikanni royalfm 95.1 ilorin nibiti ati maa n fe mon bose nlo lodo yin, e je ki atun jumon jose eto ti aaro yi. LET’S GO THERE!!!


Reader's opinions

Leave a Reply


Current track

Title

Artist

Background